Orin Dafidi 19:13-14 BIBELI MIMỌ (BM)

13. Pa èmi iranṣẹ rẹ mọ́ kúrò ninu ẹ̀ṣẹ̀ àmọ̀-ọ́n-mọ̀-dá;má jẹ́ kí wọ́n jọba lórí mi.Nígbà náà ni ara mi yóo mọ́,n kò sì ní jẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ ńlá.

14. Jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ẹnu mi, ati àṣàrò ọkàn mijẹ́ ìtẹ́wọ́gbà ní ojú rẹ,OLUWA ibi ààbò mi ati olùràpadà mi.

Orin Dafidi 19