Orin Dafidi 149:8-9 BIBELI MIMỌ (BM)

8. láti fi ẹ̀wọ̀n de àwọn ọba orílẹ̀-èdè mìíràn,ati láti fi ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ de àwọn ọlọ́lá wọn;

9. láti ṣe ìdájọ́ wọn gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀.Ògo gbogbo àwọn olódodo nìyí.Ẹ yin OLUWA!

Orin Dafidi 149