Orin Dafidi 128:5-6 BIBELI MIMỌ (BM)

5. Kí OLUWA bukun ọ láti Sioni!Kí o máa rí ire Jerusalẹmuní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.

6. Kí o máa rí arọmọdọmọ rẹ.Kí alaafia máa wà ní Israẹli.

Orin Dafidi 128