Orin Dafidi 124:6-8 BIBELI MIMỌ (BM) Ọpẹ́ ni fún OLUWA,tí kò fi wá ṣe ẹran ìjẹ fún wọn. A ti yọ, bí ẹyẹ tí ó yọ ninu okùn