Orin Dafidi 123:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ìwọ ni mo gbé ojú sókè sí,ìwọ tí o gúnwà ní ọ̀run.

2. Wò ó, bí iranṣẹkunrin ti máa ń wo ojú oluwa rẹ̀,tí iranṣẹbinrin sì máa ń wo ojú oluwa rẹ̀,bẹ́ẹ̀ ni à ń wo ojú OLUWA, Ọlọrun wa,títí tí yóo fi ṣàánú wa.

3. Ṣàánú wa, OLUWA, ṣàánú wa,ẹ̀gàn yìí ti pọ̀ jù!

Orin Dafidi 123