Orin Dafidi 115:17-18 BIBELI MIMỌ (BM)

17. Àwọn òkú kò lè yin OLUWA,àní àwọn tí wọ́n ti dákẹ́ ninu ibojì.

18. Ṣugbọn àwa yóo máa yin OLUWA,láti ìsinsìnyìí lọ, ati títí laelae.Ẹ máa yin OLUWA.

Orin Dafidi 115