Orin Dafidi 113:7-9 BIBELI MIMỌ (BM)

7. Ó gbé talaka dìde láti inú erùpẹ̀,ó sì gbé aláìní sókè láti orí eérú,

8. láti mú wọn jókòó láàrin àwọn ìjòyè,àní, àwọn ìjòyè àwọn eniyan rẹ̀.

9. Ó sọ àgàn di ọlọ́mọ,ó sọ ọ́ di abiyamọ onínúdídùn.Ẹ máa yin OLUWA.

Orin Dafidi 113