Orin Dafidi 113:4-6 BIBELI MIMỌ (BM)

4. OLUWA ju gbogbo orílẹ̀-èdè lọ,ògo rẹ̀ sì ga ju ọ̀run lọ.

5. Ta ló dàbí OLUWA Ọlọrun wa,tí ó gúnwà sí òkè ọ̀run,

6. ẹni tí ó bojú wo ilẹ̀láti wo ọ̀run ati ayé?

Orin Dafidi 113