Nọmba 6:26-27 BIBELI MIMỌ (BM)

26. Kí OLUWA bojúwò yín,kí ó sì fún yín ní alaafia.’

27. “Bẹ́ẹ̀ ni wọn óo fi orúkọ mi súre fún àwọn ọmọ Israẹli, n óo sì bukun wọn.”

Nọmba 6