Nọmba 34:23-25 BIBELI MIMỌ (BM) Láti inú ẹ̀yà Manase, a yan Hanieli ọmọ Efodu. Láti inú ẹ̀yà Efuraimu, a yan Kemueli ọmọ Ṣifitani.