Nọmba 34:22-24 BIBELI MIMỌ (BM)

22. Láti inú ẹ̀yà Dani, a yan Buki ọmọ Jogili.

23. Láti inú ẹ̀yà Manase, a yan Hanieli ọmọ Efodu.

24. Láti inú ẹ̀yà Efuraimu, a yan Kemueli ọmọ Ṣifitani.

Nọmba 34