Nọmba 33:30-33 BIBELI MIMỌ (BM)

30. Láti Haṣimona wọ́n lọ sí Moserotu.

31. Láti Moserotu wọ́n lọ sí Bene Jaakani.

32. Láti Bene Jaakani wọ́n lọ sí Hori Hagidigadi.

33. Láti Hori Hagidigadi wọ́n lọ sí Jotibata.

Nọmba 33