Nọmba 17:11-13 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Mose sì ṣe bí OLUWA ti pàṣẹ fún un.

12. Àwọn ọmọ Israẹli bá sọ fún Mose pé, “A gbé! Gbogbo wa ni a óo ṣègbé.

13. Ẹnikẹ́ni tí ó bá súnmọ́ ibi mímọ́ yóo kú, ṣé gbogbo wa ni a óo ṣègbé ni?”

Nọmba 17