Nọmba 12:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) Miriamu ati Aaroni sọ̀rọ̀ òdì sí Mose nítorí pé ó fẹ́ ọmọbinrin ará Kuṣi ní iyawo. Wọn ń wí pé