Nahumu 3:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ìlú tí ń ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ gbé!Ìlú tí ó kún fún irọ́ ati ìkógun,tí àwọn adigunjalè kò fi ìgbà kan dáwọ́ dúró níbẹ̀!

2. Pàṣán ń ró, ẹṣin ń yan,kẹ̀kẹ́ ogun ń pariwo!

Nahumu 3