Luku 4:30-32 BIBELI MIMỌ (BM)

30. Ṣugbọn ó la ààrin wọn kọjá, ó bá tirẹ̀ lọ.

31. Jesu bá lọ sí Kapanaumu, ìlú kan ní ilẹ̀ Galili. Ó ń kọ́ àwọn eniyan lẹ́kọ̀ọ́ ní Ọjọ́ Ìsinmi.

32. Ẹnu yà wọ́n sí ẹ̀kọ́ rẹ̀, nítorí pẹlu àṣẹ ni ó fi ń sọ̀rọ̀.

Luku 4