Luku 24:48-50 BIBELI MIMỌ (BM)

48. Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí nǹkan wọnyi.

49. N óo rán ẹ̀bùn tí Baba mi ṣe ìlérí sí orí yín. Ṣugbọn ẹ dúró ninu ìlú yìí títí agbára láti òkè wá yóo fi sọ̀kalẹ̀ sórí yín.”

50. Jesu bá kó wọn jáde lọ sí Bẹtani. Ó gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè, ó súre fún wọn.

Luku 24