Luku 1:79-80 BIBELI MIMỌ (BM)

79. láti tan ìmọ́lẹ̀ sí àwọn tí ó wà ní òkùnkùnati àwọn tí ó jókòó níbi òjìji ikú,láti fi ẹsẹ̀ wa lé ọ̀nà alaafia.”

80. Ọmọ náà ń dàgbà, ó sì ń lágbára sí i lára ati lẹ́mìí. Ilẹ̀ aṣálẹ̀ ni ó ń gbé títí di àkókò tí ó fara han àwọn eniyan Israẹli.

Luku 1