Lefitiku 14:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA sọ fún Mose pé,

2. “Òfin tí ó jẹmọ́ ti ọjọ́ ìwẹ̀nùmọ́ adẹ́tẹ̀ nìyí: kí wọ́n mú adẹ́tẹ̀ náà wá sí ọ̀dọ̀ alufaa.

Lefitiku 14