Kronika Kinni 8:1-4 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Bẹnjamini bí ọmọkunrin marun-un, Bela ni àkọ́bí, lẹ́yìn rẹ̀ ni Aṣibeli,

2. lẹ́yìn rẹ̀, Ahara, lẹ́yìn rẹ̀, Nohahi, àbíkẹ́yìn rẹ̀ ni, Rafa.

3. Àwọn ọmọ Bela ni: Adari, Gera, ati Abihudi,

4. Abiṣua, Naamani, ati Ahoa,

Kronika Kinni 8