Kronika Kinni 6:7-10 BIBELI MIMỌ (BM)

7. Meraiotu bí Amaraya, Amaraya sì bí Ahitubu.

8. Ahitubu ni baba Sadoku, Sadoku bí Ahimaasi,

9. Ahimaasi bí Asaraya, Asaraya sì bí Johanani.

10. Johanani bí Asaraya (òun ni alufaa tí ó wà ninu tẹmpili tí Solomoni kọ́ sí Jerusalẹmu).

Kronika Kinni 6