Kronika Kinni 5:3-5 BIBELI MIMỌ (BM)

3. Àwọn ọmọ Reubẹni, àkọ́bí Jakọbu, ni: Hanoku, Palu, Hesironi ati Kami.

4. Joẹli ni ó bí Ṣemaya, Ṣemaya bí Gogu, Gogu bí Ṣimei;

5. Ṣimei bí Mika, Mika bí Reaaya, Reaaya bí Baali;

Kronika Kinni 5