Kronika Kinni 3:16-18 BIBELI MIMỌ (BM)

16. Jehoiakimu bí ọmọ meji: Jekonaya ati Sedekaya.

17. Àwọn ọmọ Jehoiakini, ọba tí a mú lẹ́rú lọ sí Babiloni nìwọ̀nyí: Ṣealitieli,

18. Malikiramu, Pedaaya, ati Ṣenasari, Jekamaya, Hoṣama ati Nedabaya.

Kronika Kinni 3