Kronika Kinni 3:10-15 BIBELI MIMỌ (BM)

10. Àwọn ọmọ Solomoni ọba nìwọ̀nyí: Rehoboamu, Abija, Asa, ati Jehoṣafati;

11. Joramu, Ahasaya, ati Joaṣi;

12. Amasaya, Asaraya, ati Jotamu;

13. Ahasi, Hesekaya, ati Manase,

14. Amoni ati Josaya.

15. Orúkọ àwọn ọmọ Josaya mẹrẹẹrin, bí wọ́n ṣe tẹ̀lé ara wọn ni: Johanani, Jehoiakimu, Sedekaya ati Ṣalumu.

Kronika Kinni 3