Kronika Kinni 3:10-13 BIBELI MIMỌ (BM) Àwọn ọmọ Solomoni ọba nìwọ̀nyí: Rehoboamu, Abija, Asa, ati Jehoṣafati; Joramu, Ahasaya, ati Joaṣi;