Kronika Kinni 24:7-16 BIBELI MIMỌ (BM)

7. Gègé tí wọ́n kọ́kọ́ ṣẹ́ mú Jehoiaribu, ekeji mú Jedaaya. Gègé sì mú àwọn yòókù wọnyi tẹ̀léra wọn báyìí:

8. Harimu, Seorimu;

9. Malikija, Mijamini;

10. Hakosi, Abija,

11. Jeṣua, Ṣekanaya;

12. Eliaṣibu, Jakimu,

13. Hupa, Jeṣebeabu;

14. Biliga, Imeri,

15. Hesiri, Hapisesi;

16. Petahaya, Jehesikeli,

Kronika Kinni 24