Kronika Kinni 23:18-21 BIBELI MIMỌ (BM)

18. Iṣari bí ọmọkunrin kan, Ṣelomiti, tí ó jẹ́ olórí ìdílé rẹ̀.

19. Heburoni bí ọmọ mẹrin: Jeraya, tí ó jẹ́ olórí, lẹ́yìn rẹ̀ ni Amaraya, Jahasieli, Jekameamu.

20. Usieli bí ọmọ meji: Mika, tí ó jẹ́ olórí, ati Iṣaya.

21. Merari bí ọmọkunrin meji: Mahili ati Muṣi. Mahili bí ọmọkunrin meji: Eleasari ati Kiṣi,

Kronika Kinni 23