Kronika Kinni 2:38-41 BIBELI MIMỌ (BM)

38. Obedi ni baba Jehu, Jehu sì ni baba Asaraya.

39. Asaraya ni ó bí Helesi, Helesi ni ó sì bí Eleasa.

40. Eleasa bí Sisimai, Sisimai bí Ṣalumu;

41. Ṣalumu bí Jekamaya, Jekamaya sì bí Eliṣama.

Kronika Kinni 2