Kronika Kinni 2:14-16 BIBELI MIMỌ (BM)

14. Netaneli ati Radai;

15. Osemu ati Dafidi.

16. Àwọn arabinrin wọn ni Seruaya ati Abigaili. Seruaya yìí ló bí Abiṣai, Joabu ati Asaheli.

Kronika Kinni 2