Kronika Kinni 2:11-15 BIBELI MIMỌ (BM)

11. Nahiṣoni ni baba Salima; Salima ni ó bí Boasi,

12. Boasi bí Obedi, Obedi sì bí Jese.

13. Jese bí ọmọ meje; orúkọ wọn nìyí bí wọ́n ṣe tẹ̀lé ara wọn: Eliabu ni àkọ́bí, lẹ́yìn náà Abinadabu ati Ṣimea;

14. Netaneli ati Radai;

15. Osemu ati Dafidi.

Kronika Kinni 2