Kronika Kinni 11:40-43 BIBELI MIMỌ (BM)

40. Ira, ará Itiri, ati Garebu ará Itiri,

41. Uraya, ará Hiti, ati Sabadi, ọmọ Ahilai,

42. Adina, ọmọ Ṣisa, láti inú ẹ̀yà Reubẹni, olórí kan láàrin ẹ̀yà Reubẹni, pẹlu ọgbọ̀n àwọn ọmọ ogun rẹ̀;

43. Hanani, ọmọ Maaka, ati Joṣafati, ará Mitini;

Kronika Kinni 11