Kronika Kinni 11:32-36 BIBELI MIMỌ (BM)

32. Hurai, ará etí odò Gaaṣi, ati Abieli, ará Aribati;

33. Asimafeti, ará Bahurumu, ati Eliaba ará Ṣaaliboni;

34. Haṣemu, ará Gisoni, ati Jonatani, ọmọ Ṣagee, ará Harari;

35. Ahiamu, ọmọ Sakari, ará Harari, ati Elifali, ọmọ Uri;

36. Heferi, ará Mekerati, ati Ahija, ará Peloni;

Kronika Kinni 11