Kronika Kinni 11:30-34 BIBELI MIMỌ (BM)

30. Maharai, ará Netofa, ati Helodi, ọmọ Baana, ará Netofa;

31. Itai, ọmọ Ribai, ará Gibea, láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini, ati Bẹnaya, ará Piratoni;

32. Hurai, ará etí odò Gaaṣi, ati Abieli, ará Aribati;

33. Asimafeti, ará Bahurumu, ati Eliaba ará Ṣaaliboni;

34. Haṣemu, ará Gisoni, ati Jonatani, ọmọ Ṣagee, ará Harari;

Kronika Kinni 11