Kronika Kinni 1:51-54 BIBELI MIMỌ (BM)

51. Àwọn ìjòyè ẹ̀yà Edomu nìwọ̀nyí: Timna, Alia, ati Jeteti;

52. Oholibama, Ela, ati Pinoni,

53. Kenasi, Temani, ati Mibisari,

54. Magidieli ati Iramu.

Kronika Kinni 1