Kọrinti Kinni 1:30-31 BIBELI MIMỌ (BM)

30. Nípa iṣẹ́ Ọlọrun, ẹ̀yin wà ní ìṣọ̀kan pẹlu Kristi Jesu. Òun ni Ọlọrun fi ṣe ọgbọ́n wa ati òdodo wa. Òun ni ó sọ wá di mímọ́, tí ó dá wa nídè.

31. Nítorí náà, gẹ́gẹ́ bí ó ti wà ní àkọsílẹ̀ pe:“Ẹni tí ó bá fẹ́ ṣe ìgbéraga,kí ó ṣe ìgbéraga nípa ohun tí Oluwa ṣe.”

Kọrinti Kinni 1