Joṣua 15:56-58 BIBELI MIMỌ (BM)

56. Jesireeli, Jokideamu, Sanoa,

57. Kaini, Gibea, ati Timna, gbogbo ìlú ati ìletò wọn jẹ́ mẹ́wàá.

58. Halihuli, Betisuri, Gedori,

Joṣua 15