Joṣua 12:9-13 BIBELI MIMỌ (BM)

9. Àwọn ọmọ Israẹli ṣẹgun gbogbo ọba àwọn ìlú wọnyi: Jẹriko ati Ai, lẹ́bàá Bẹtẹli;

10. Jerusalẹmu ati Heburoni,

11. Jarimutu ati Lakiṣi;

12. Egiloni ati Geseri,

13. Debiri ati Gederi;

Joṣua 12