Johanu 2:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) Ní ọjọ́ kẹta, wọ́n ń ṣe igbeyawo kan ní Kana, ìlú kan ní Galili. Ìyá Jesu wà níbẹ̀. Wọ́n pe Jesu ati