Jobu 19:1-4 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Jobu bá dáhùn, ó ní,

2. “Ẹ óo ti ni mí lára pẹ́ tó,tí ẹ óo máa fi ọ̀rọ̀ yín bà mí ninu jẹ́?

3. Ẹ kẹ́gàn mi ní àìníye ìgbàojú kò tilẹ̀ tì yín láti ṣẹ̀ mí?

4. Bí ó bá tilẹ̀ jẹ́ pé lótìítọ́ ni mo ṣẹ̀,ṣebí ara mi ni àṣìṣe mi wà?

Jobu 19