Jeremaya 30:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA Ọlọrun Israẹli bá Jeremaya sọ̀rọ̀:

2. Ó ní, “Kọ gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo ti sọ fún ọ sinu ìwé,

Jeremaya 30