Jeremaya 11:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA bá èmi Jeremaya sọ̀rọ̀,

2. ó ní, “Gbọ́ ọ̀rọ̀ majẹmu yìí, kí o sì sọ ọ́ fún àwọn ọmọ Juda, ati àwọn tí ń gbé Jerusalẹmu.

Jeremaya 11