Jẹnẹsisi 40:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ní àkókò kan, agbọ́tí Farao, ọba Ijipti, ati olórí alásè rẹ̀ ṣẹ ọba.

2. Inú bí Farao sí àwọn iranṣẹ rẹ̀ mejeeji yìí,

Jẹnẹsisi 40