Jẹnẹsisi 36:28-30 BIBELI MIMỌ (BM)

28. Àwọn ọmọ Diṣani ni: Usi ati Arani.

29. Àwọn ìjòyè tí wọ́n ṣẹ̀ lára Hori nìwọ̀nyí: Lotani, Ṣobali, Sibeoni,

30. Diṣoni, Eseri, ati Diṣani. Àwọn ìjòyè ilẹ̀ Hori, gẹ́gẹ́ bí olórí ìdílé ìdílé wọn ní ilẹ̀ Seiri.

Jẹnẹsisi 36