Jẹnẹsisi 31:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) Jakọbu gbọ́ pé àwọn ọmọ Labani ń sọ pé òun ti gba gbogbo ohun tíí ṣe ti baba wọn, ninu ohun ìní