Jẹnẹsisi 10:14-16 BIBELI MIMỌ (BM)

14. Patirusimu, Kasiluhimu, (lọ́dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistia ti ṣẹ̀) ati Kafitorimu.

15. Àkọ́bí Kenaani ni Sidoni, òun náà ni ó bí Heti.

16. Kenaani yìí kan náà ni baba ńlá àwọn ará Jebusi, àwọn ará Amori, àwọn ará Girigaṣi,

Jẹnẹsisi 10