Isikiẹli 20:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ní ọjọ́ kẹwaa oṣù karun-un, ọdún keje tí a ti wà ní ìgbèkùn, àwọn àgbààgbà Israẹli kan wá láti wádìí ọ̀rọ̀ lọ́dọ̀ OLUWA, wọ́n sì jókòó níwájú mi.

2. OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní,

Isikiẹli 20