Ìfihàn 16:20-21 BIBELI MIMỌ (BM)

20. Omi bo gbogbo àwọn erékùṣù, a kò sì rí ẹyọ òkè kan mọ́.

21. Yìnyín ńláńlá tí ó tóbi tó ọlọ ata wá bẹ̀rẹ̀ sí bọ́ lu eniyan láti ojú ọ̀run. Àwọn eniyan wá ń sọ ọ̀rọ̀ àfojúdi sí Ọlọrun nítorí ìparun tí yìnyín yìí ń fà, nítorí ó ń ṣe ọpọlọpọ ijamba.

Ìfihàn 16