Ìṣe Àwọn Aposteli 2:1-2 BIBELI MIMỌ (BM) Ní ọjọ́ Pẹntikọsti, gbogbo wọn wà pọ̀ ní ibìkan náà. Lójijì ìró kan dún láti ọ̀run