Ìṣe Àwọn Aposteli 12:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ní àkókò náà Hẹrọdu ọba bẹ̀rẹ̀ sí ṣe inúnibíni sí àwọn kan ninu ìjọ.

2. Ó bẹ́ Jakọbu arakunrin Johanu lórí.

Ìṣe Àwọn Aposteli 12