Ìṣe Àwọn Aposteli 1:25-26 BIBELI MIMỌ (BM)

25. kí ó lè gba iṣẹ́ yìí ati ipò aposteli tí Judasi fi sílẹ̀ láti lọ sí ààyè tirẹ̀.”

26. Wọ́n bá ṣẹ́ gègé. Gègé bá mú Matiasi. Ó bá di ọ̀kan ninu àwọn aposteli mọkanla.

Ìṣe Àwọn Aposteli 1